Adabo Ebo de Tablero

April 27, 2017 | Author: William Rodríguez | Category: N/A
Share Embed Donate


Short Description

Este documento nos muestra la forma de hacer un Ebo de Tablero... el cual encuentro muy completo. Ogbo Ato Ase O...

Description

Ebo de Tablero Por Babalawo Ifadiyimu Surulere Estos rezos se rezan antes de comenzar el ebo

Otrupon D i Otúrúpọ̀n ‘Di, eye ṣí Otúrúpọ̀n ‘Di, eye bà Otúrúpọ̀n ‘Di, eye ṣí eye ò ṣí Otúrúpọ̀n ‘Di, eye bà ò bà Otúrúpọ̀n ‘Di, eye ni ò ta kánká, kó gun gi D’ ifa fun Òrúnmilà Ni jó àwọn eleyé ilé iyá rẹ̀ rán ni wá péè Ajé ilé oṣo ilé, e m’owùn mi Eleye Kií bá eleye wíjó Otrupon Di, un ave sale volando Otrupon Di, un ave se posa Otrupon Di, si el ave vuela o no Otrupon, si el ave se posa o no Otrupon Di, es el ave que es lenta Para trepar el árbol Otrupon Di, es el ave que no vuela Lo suficientemente de prisa La adivinación hecha a Orunmila Cuando sus parientes maternos Enviaron por el Brujas, hechiceros, todos ustedes Conocen mi voz Brujas, hechiceros todos ustedes Reconocen mi voz Las aves místicas no pelean entre si El respeto entre entidades Podersosas

Okana Sa Mano derecha Otún pẹ̀lé Awo won l’óde Abá D’ifa fun won l’óde Abá Wón ji, ekú ajé ni wón nsun Wón ni ki wón rúbọ l’óde Abá

Won ni ajé l’ówó

Mano izquierda Osi pẹ̀lẹ́ Awo won l’óde Aboṣe Wón rú’bo l’óde Aboṣe Wón bi mo púpọ̀ l’óde Aboṣe Ambas manos Ati ọ̀tún àti òsi, ki i rú ebo à i ma da D’ifá fun àṣéwélé T i ṣe omokùnrin d’èpè nù Ni jó ti wón nre igbó àdéwúre Dèpènù, Dèpènù, à bá da ègún, da èpè lé awo l’óri, kò lè jà ṣéwélé mà dé ò, omodé ‘kùnrin dèpènù La palma derecha, pele (mano acepta mis saludos) Su Babalawo en el pueblo de Aba La adivinación hecha a ellos en el pueblo de Aba Lloraban por falta de riquezas Les fue aconsejado hacer el ebo en el pueblo de Aba Hicieron el ebo en el pueblo de Aba Todos obtuvieron riquezas, todos tuvieron ire La palma izquierda, pele (mano izquierda acepta mis saludos) Su Babalawo en el pueblo de Abose Lloraban por la falta de hijos Les fue aconsejado hacer el ebo en el pueblo de Abose Hicieron el ebo en el pueblo de Abose Todos tuvieron muchos hijos en el pueblo de Abose Ambas manos jamás pueden hacer el ebo sin que este las acepte La adivinación hecha a asewele El hijo del repelente de hechizos Cuando se dirigían al bosque de “te mostraré mi gratitud cuando regrese” Repelente de hechizos, repele maldiciones, hechizos y otros Pronunciamientos maléficos que puedan estar invocados En El Awo. Oh! Aqui viene Asewele, el repelente de hechizos

Ogunda Owonrin Ti wọn nṣe olóri orò n’ Ifẹ̀ Njẹ́, kinni à báa bọ ni Ifẹ̀?

Iṣẹ̀ṣe ni à bá bọ, iki a tó bọ Oriṣà Baba ẹni ni iṣẹ̀ṣẹ ẹni Iyá ẹni ni iṣẹ̀ṣẹ ẹni Ori ẹni ni iṣẹ̀ṣẹ ẹni Ikin ẹni ni iṣẹ̀ṣẹ ẹni Odùmàrè ni iṣẹ̀ṣẹ Iṣẹ̀ṣẹ, mo júbà ki ntó s’ ẹbọ

Otura Ika Erigi lawo Agbasà Dia fún wọn ní Iṣẹ̀ṣe-Agéré Nijọ́ ti wọ̀n kó ohun ẹbọ sílẹ̀ Ti wọ́n nwá Bàbáláwo ó loro A ró’hun ẹbọ lónìí, a ró’hun ẹbọ Erìgì lawo Agbasà Ifá a róhun ẹbọ Ekọ tónbẹ nílẹ̀ yìi nkọ́ Ohun ẹbọ níí ṣe Erìgì lawo Agbasà Ifá a róhun ẹbọ Omi tó nbẹ níẹ̀ yìi nkọ Ohun ẹbọ níí ṣe Erìgì lawo Agbasà Ifá a róhun ẹbọ Epo tó nbẹ nílẹ̀ yìí nkọ́ Ohun ẹbọ níí ṣe Erìgì lawo Agbasà Ifá a róhun ẹbọ Oti tí nbẹ nílẹ̀ yìí nkọ́ Ohun ẹbọ níí ṣe Erìgì lawo Agbasà Ifá a róhun ẹbọ .........sigue repitiendo los m ateriales del ebo..........

Odi Ogbe Adabọ, jọ̀ ọ́ jẹ́ ki ẹbọ ó dà fún ẹlẹ́bọ ò adabọ Ti ọ bá tó ẹbi, ki ẹ jẹ́é ó fin Adabọ, jọ̀ ọ́ jẹ́ ki ẹbọ ó dà fún ẹlẹ́bọ ò adabọ Ni Ikọ Awúsí ni ilé Ifá Adabọ, jọ̀ ọ́ jẹ́ ki ẹbọ ó dà fún ẹlẹ́bọ ò adabọ Ni Idòròmàwúsẹ̀ ni ilé Ifá Adabọ, jọ̀ ọ́ jẹ́ ki ẹbọ ó dà fún ẹlẹ́bọ ò adabọ Ki l’ẹbọ ó ṣe ma dà fún ẹlẹ́bọ

Adà kan, àdà kàn ni ẹbọ ó ma dà fún ẹlẹ́bọ Adà kan, àdà kàn ni ẹbọ pápàá dà Aquí se comienza el ebo

Oṣe Otura Pénpé lẹsẹ̀ẹ̀ tùbú Elà agẹmọ ni ò tó gèlè Ibá tó gèlè Nbá mú relé lọ̀ọ́ wé Diá fún Awúrelà Tí n ṣawo ròde Ijẹ̀bú Apèjin làá pe Onírú Apèjin làá pe Oníyọ̀ Apèlà, àpèlà làá pe Awúrelà Ni Ijẹbú Oṣẹ́ Awúrelà. Awo ire ni o Odun Toyale

Oyekun Ogbe Ewo là ní ṣe ni ikọ̀kọ̀ Ti ojú Olódùmarẹ ọ̀ tó Dia fún Jẹ́nmí Tii ṣ’ọ̀mọ Oṣun Ewo là ní ṣe ni ikọ̀kọ̀ Ti ojú Olódùmarẹ ọ̀ tó Dia fún Emí-laá-yín Tii ṣ’ọ̀mọ Obàtálá Jẹ́nmí ọmọ Oṣun lòó ṣe Emí-laá-yin iwọ lọmọ Obàtálá Ifá ni yóó oju u rẹ̀ sí gbangba o Si la persona vino Ayewo durante la consulta se reza el Omo Iya

Iwori Ofun Enini bẹ́lẹ́bẹ́lẹ́ níí werí ẹmó Tòtò bàlàbàlà níí wẹ̀dí àdán Agẹmo òògùn níí wẹrí ọlójá Mẹ́rindinlógún nínú ajere idẹ A díá fún Iwòri Níjọ́ ti n lọ rèé wẹrí Ofún Ori Ofún le dáa báyìí? Wọ́n ni ki Ofun ó tọ Iwòri lọ

Iwòrí bá wẹrí Ofún

Oshe Iwori Osẹ̀ pàá bi ọkọ́ Iwòri jòwòlò bíi rádun Arọ̀ ré re réè Awo ilé Orúnmilà Yóó yẹ ikú kúò lórí ọmọọ rẹ̀ Yó lọ rèé gbé e kọ́rí igi lóko Wọ́n ni bó bá ti rúbọ Ikú yẹ̀ Orùnmilà rùbọ Rezar signo del padrino, ojugbona y el propio del Awo oficiando el Ebo Rezos Mejis

Baba Ejiogbe Igbo ni igbona Odan lodan Orun Adifafun Orunmila Ni ojo ti ifa nlo ki owo abiku bo ile ni koto atitan Ni igba ti Orunmila nse abiku oto awon babalawo igbo ni igbona ati odan lodan Bosque es el bosque de fuego. Pradera es la pradera del Sol Fue los que profetizaron para Orunmila. El día en que fue a enterrar medicina Contra los abiku en un monton (se refiere a tierra) Cuando Orunmila fue perturbado por los abiku Fue donde los babalawos Bosque es bosque de fuego Y pradera es pradera del sol

Oyekun Meji Eesin gbona l’ewé tutu l’egbo li o dífá fún Márùnlelọgọ́jọ igi oko Opẹ̀ ati Ayinrẹ́ li o ru: Oromọdie ninu wọn

Nitorinaa bi iji banja Ogọ mariow a ni: Oun ṣẹbọ Oyẹ̀keẹ́ṣẹ́ Eesin gbona l’ewe tutu l’egbo Adivino Ifa para 165 árboles La palma y el árbol ayinre Sacrifico un pollo entre los árboles. Entonces, si el tornado estaba en furia, Las ramas de la joven palma declararían: “Yo he sacrificado para escapar el peligro”

Iwori Meji Ogòdò òwú sòkè odò Payín kekeeke sólóko A díá fún Alántaakùn Omọ aṣoun gbogbo Bí idán bí idán Ifá, bí idán, bí idán Ni o ṣerree tèmi fémi Ogòdò òwú sòkè odò Payín kekeeke sólóko Cuando el granjero mira El algodón del otro lado del río Pareciera que le sonríe alegremente Mostrándole su blanca dentadura Lo que le fue profetizado a la araña La descendencia de aquellos que hacen Las cosas de una forma maravillosa. Ifa en su forma maravillosa Trae todas las cosas buenas para mí. Cuando el granjero mira El algodón del otro lado del río Pareciera que le sonríe alegremente

Odi Meji Emi ẹ̀ni-òdí Iwọ ẹ̀ni-òdí Li o dífá f’Od= nigba ọtẹ Wọ́n ni: Owọ́ Odí a Ka’lu Nitorinaa ki ó rú Oja Idimọ méjì

O gbọ́ ó rú Yo soy eni-odi Tu eres eni-odi Dos eni-odi adivinaron para el fortín Durante hostilidades políticas Ellos dijeron: El fuerte rodeara el pueblo. Por lo tanto tiene que ofrecer dos paños de envoltura Y así lo hizo

Irosun Meji Ibabúrú Awoo wọn lóde Ibabúrú Ibabúrú Awoo wọn lóde Ibabúrú Ibabúrú Awo òde Ibarakata A díá fún Igbà Tí nṣawoó ròde Oyọ́ Gbogbo ilé Igbà ló gbóná Tọmọtọmọ, tobìnrintobìnrin Wọ́n ní Igbà ó rúbo Kára ó lè baá tù ú O rúbọ rán Ni ará wáá bẹ̀rẹ̀ síِ tù ú O ní Ibabúrú El sacerdote de Ifa conocido como Ibaburu Ese era el sacerdote de la ciudad de Ifa Ibaburu El sacerdote de Ifa conocido como Ibaburu Sacerdote de la ciudad de Ibaburu El mismo Ibaburu Que también era el sacerdote de la ciudad de Ibarakata Lo que fue adivinado para Igba Cuando el iba a la vieja ciudad de Oyo para adivinación Cuando todas sus crias y esposas estaban con mucha fiebre Igba se le dijo que sacrificará Para que el encontrara paz Luego de hacer el sacrificio El comenzó a tener paz

Owonrin Meji

Okúta là pàá mọ́ ṣèjẹ̀ A díá fún Jànjàsá Tíí ṣe olórí ẹgbẹ́ lọ́run Wọ́n ní kí Jànjàsá ó Mójú tó àwọn ẹgbẹ́ẹ rẹ̀ Igbàa Jànjàsá ṣe bẹ́ẹ̀ Ló bá di wí pé ó dára fún un O ní Okúta là pàá mọ́ ṣẹ̀jẹ̀ A díá fún Jànjàsá Tíí ṣe olórí ẹgbẹ́ lọ́run Erò Ipo Erò Ofà Egbẹ́ọ̀gbà ni wọ́ọ́n bọ níbẹ̀ Bó bá bí ni La piedra se rompe de repente, pero no sangra Lo que se profetizo a Janjasa Que era el líder de un grupo de camaradas en el cielo Janjasa se le dijo que cuidara a su cofradía Cuando hizo como se le dijo las cosas comenzaron a Salirle bien nuevamente El dijo: “la piedra se rompe de repente pero no sangra El era un líder del grupo de camaradas en el cielo Viajeros a la ciudad de IPO Viajeros a la ciudad de OFA A egbeogba se le debe ser sacrificado Cuando esta deidad es parte de la familia de alguien.

Obara Meji Eyí wésewése n d’ifá Eyí wésewése n d’ibò Orọ̀rẹ́ wọn ò l’ágbà nínú Gbogbo wọn ni wọn ndá wésewése Nibi awo ṣíṣe Gbogbo wọn ni wọn rí dáradára Dِá fún Ejí-Obàrà Ti yóó t’ojú Olọ́run là Wa’ye bí ọba ẹrẹ́kẹ Ebọ ni wọn ni kó ṣe O gb’ẹ́bọ, ó rú’bọ Kò pẹ́ kò jínná E wá bá ni ni jéẹ̀bútú ire

Los pequeñitos estan consultando Ifa Y los pequeños sostienen los ibo (determinantes) Oroore las aves no tienen mayores entre ellos Todos ellos son pequeñitos y del mismo tamaño Cuando están haciendo rituales de Ifa Es hermoso mirarlos a todos Estas fueron las declaraciones de Ifa para Eji-Obara Que vendrá con prosperidad a la tierra del cielo Como el Oba de los ricos Se le dijo que ofreciera ebo El lo hizo No muy tarde y no muy lejano Unete a nosotros en medio de todo el Ire.

Okana Meji Okan bàlàbàlá Awo Omú ló díá f’Omú Omú n’tọ̀run bọ̀ wálé Ayé O nrayé àgbéjó Ebọ ni wọ́n ní kó wáá ṣe O gb’ẹ́bọ, ó rú’bọ Kò pẹ́, kò jínnà E wá bá’ni b’ẹ́wá E wá wo’re o Aquello que se mece y es adorado Eso fue lo que Ifá profetizó a Omu, (el seno) Cuando venía del cielo a la tierra Y venía a disfrutar la vida siendo acariciada Se le dijo que hiciera Ebo (sacrificio) Ella así lo hizo Pronto, no muy lejano Unanse a nosotros alrededor de la belleza Vengan y obtengan todo el Ire de la vida

Ogunda Meji Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Díá fún Orúnmílà Ifá nlọ̀ọ́ ra Osányín l’ẹ́rú Ebọ ni wọ́n ni kó ṣẹ O gb’ẹ́bọ, ó rú’bọ Eyí ewé ajé

Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Ewo ni n ó ro nù? Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Eyí ewé aya (si el ebo es para mujer se substituye con oko) Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Ewo ni n ó ro nù? Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Eyí ewé ọmọ Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Ewo ni n ó ro nù? Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Eyí ewé àíkú Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Ewo ni n ó ro nù? Gbinrin bí ítí Bí ítí gbinrin Gbinrin bi iti Bi Iti gbinrin Estos fueron los Babalawos Que adivinaron para Orunmila Cuando este iba a comprar a Osanyin Como su esclavo Se le dijo que hiciera sacrificio (ebo) El así lo hizo Esta es la hoja de las riquezas Todos alaben a Gbinrin bi iti Y a Bi iti gbinrin Cual debo despejar Todos alaben a Gbinrin bi iti Y a Bi iti gbinrin Esta es la hoja para conseguir esposa Todos alaben a Gbinrin bi iti Y a Bi iti gbinrin Cual debo despejar Todos alaben a Gbinrin bi iti

Y a Bi iti gbinrin Esta es la hoja para tener hijos Todos alaben a Gbinrin bi iti Y a Bi iti gbinrin Cual debo despejar Todos alaben a Gbinrin bi iti Y a Bi iti gbinrin Esta es la hoja para la longevidad Todos alaben a Gbinrin bi iti Y a Bi iti gbinrin Cual debo despejar Todos alaben a Gbinrin bi iti Y a Bi iti gbinrin Cual debo despejar Todos alaben a Gbinrin bi iti Y a Bi iti gbinrin

Osa Meji Osá yóó, Awo Ayé Díá fún Ayé Nijọ Ayé le kokoko bi ọta Ebọ ni wọ́n ni kó wáá ṣe O gb’ẹ́bọ, ó ru’bọ Ayé wá jẹ’gẹ̀dẹ̀ tán Ayé n tutù ú bọ Jẹ’gẹdẹ, jẹ’gẹ̀dẹ̀ Osa yoo el Awo de Aye, la madre tierra El fue el el Awo que consultó Ifa para Aye Cuando Aye estaba tan dura como granito Se le dijo que ofreciera ebo Ella así lo hizo Después de comer guineos Aye se puso muy fresca y cómoda Je’gede, je’gede. Come tus propios guineos

Ika Meji Eni kiini iká Eni keji iká Igba iká di méji ó di òdodo Díá fún Oba Ti yóó bi Orọ̀ l’ọ́mọ Ebọ ni wọ́n ni kó wáá ṣe

O gb’ẹ́bọ, ó ru’bọ Kò pẹ́ kò jinnà E wó bá ni ni wọ̀wọ́ ire Kinló wá s’èjiká di méji Awo rere Ló s’èjiká di méji Awo rere El primero es Ika El segundo también es Ika Cuando Ika se presenta en pares Entonces tenemos un verdadero Ika Meji Este es el mensaje para el Oba Quién dará el nacimiento a Oro Se le dijo que ofreciera ebo El así lo hizo Pronto, no muy lejano Uneté a nosotros en el medio de todo el Ire Que convierte Ika en dos Un buen Awo Fue el responsable de conseguirnos Ika Meji Un buen Awo

Otrupon Meji Ibábá Wo Egúngún Ikọ̀kọ̀ Awo Orò Gbangba l’Ogèdèngbé nṣawo l’awo Ilé Orúnmílà Díá fún Ejí-Otúrú Ti nt’ọ̀run bọ̀ wá’lé Ayé Ebọ ni wọ́n ni kó wáá ṣe O gb’ẹ́bọ, ó rú’bọ Kò pẹ́, Kò jinnà E wáá bá ni l’árùúṣẹ́ ogun Secretividad es el camino de Egungun Altamente protegido en la oscuridad es la practica de Oro La apertura es la forma en que se conduce Orunmila Estos fueron los mensajes de Ifa para Eji-Oturu Cuando venía del cielo a la tierra Se le dijo que ofreciera ebo El así lo hizo Pronto y no muy lejano Unete a nosotros cuando seamos

Bendecidos con la victoria Otura Meji Ajenje ni’règún, ẹgbọrọ ni’dè Díá fún Orúnmílà Ifá nt’ọ̀run bọ̀ wá’yé Ebọ ni wọ́n ni kó wáá ṣe N ó l’ówó l’ówó nílé Ayé ki n tóó wá ò Egbọrọ ni’dè Ajenje ni’règún, ẹgbọrọ ni’dè N ó l’áya-m’áya ni’lé Ayé ki n tóó wá ò Ajenje ni’règún, ẹgbọrọ ni’dè Egbọrọ ni’dè N ó bi’mọlé’mọ ni’lé Ayé ki n tóó wá ò Ajenje ni’règún, ẹgbọrọ ni’dè Egbọrọ ni’dè N ó j’ogbó-j’atọ́ ni’lé Ayé ki n tóó wá ò Ajenje ni’règún, ẹgbọrọ ni’dè Egbọrọ ni’dè N ó nire gbogbo ni’lé Ayé ki n tóó wá ò Ajenje ni’règún, ẹgbọrọ ni’dè Egbọrọ ni’dè Kò pẹ́, Kò jínnà E wá bá ni l’átolé Ire gbogbo Atólé Ire gbogbo làá bá ni l’ẹ́sẹ̀ Obàríṣa Ajenje ni’regun egboro ni de Fue el Awo que adivino Ifa Para Orunmila Cuando venía del cielo a la tierra Se le aconsejó que hiciera sacrificio El así lo hizo Yo recibiré las bendiciones de riquezas Antes de que regrese Egboro ni’de Ajenje ni’regun egboro ni de Yo recibiré las bendiciones de una buena esposa Antes de que regrese Egboro ni’de Ajenje ni’regun egboro ni de Yo recibiré las bendiciones de buenos hijos Antes de que regrese Egboro ni’de

Ajenje ni’regun egboro ni de Yo recibiré las bendiciones de larga vida Antes de que regrese Egboro ni’de Ajenje ni’regun egboro ni de Yo recibiré las bendiciones de todos los ire Antes de que regrese Egboro ni’de Ajenje ni’regun egboro ni de Pronto, y no muy lejos Ven y únete a nosotros en medio de Todos los Ire en la vida Esa es la garantía que obtenemos Si seguimos a Ifa, el Oba de todos los Orisa

Irete Meji Okọ rẹ́ Aya rẹ́ Díá fún Okẹ̀rẹ̀ jẹ̀gbẹ̀ Ti yóò fẹ obínrin Ikú tán Ti yóò f’obí mẹ́fà kẹ Ebọ ni wọ́n ni kó wáà ṣe O gb’ẹ́bọ, O rú’bọ Kò pé kò jinnà E wá bá ni lárùúṣé Ogun Ifá dé aláṣẹ Opẹ̀ ab’iṣẹ wàrà Que la paz sea con el esposo Y con la esposa también Este fue el mensae a Okere jegbe (la ardilla) Quién arrebatará la esposa de Iku Y usado seis nueces de kola para aplacarlo Se le aconsejó que hiciera sacrificio El lo hizó Pronto, no muy lejano Ven y encuéntranos donde Celebramos la victoria Aquí viene Ifa La palma sagrada que se Manifiesta con eficacia

Oṣe Meji

Ewé ilá ba’lẹ̀, o f’ara jọ ewé Adé Ewé Adé ba’lẹ̀, o f’ara jọ ewé Ilá Ewé ògùngun ló ba’lẹ̀, Ó ró gbàámído- gbàámído O ró gbàálúkọkọ-gbàálúkọkọ Díá fún Ajé O ńw’ọ́kọ Imọ́ràn-án yàn kíri Díá fún Orúnmílà Efá ńf’omi oju sùngbérè Ajé ṣuuruṣu Ebọ ní wọ́n ní kó wáá ṣe Wọ́n gb’ẹ́bọ, wọ́n rú’bo Ifá l’émi ó kẹ ‘bòosí Ajé Ajé ló sọ mí d’ọba N ó ké ‘bòosí Ajé Ajé ní Ifá má ké ‘bòosí i mi mo Iwọ lo sọ mi d’ọlọ́mo Ifá má ké ‘bòosí i mi mo Cuando las hojas de okra caen, Se asemejan a las de Ade Cuando las hojas de Ade caen Se asemejan a las de okra Cuando las hojas de ogungun caen Hacen un sonido crujiente Esto fue lo adivinado a Aje Cuando estaba en busqueda De un esposo compatible Ifa tambien declaro Lo mismo a Orunmila Se les aconsejó que hicieran ebo Ellos lo hicieron Ifa dice que debo alabar a Aje Aje me ha hecho tan próspero Yo seguramente alabaré a Aje Aje le dijo a Orunmila que No le alabara Porque el la había hecho Una orgullosa madre Orunmila no me alabes más Todas esas alabanzas Pertenecen a Ifa

Ofun Meji

Ode ní d’áró Odẹ̀dẹ̀ ní ran’kùn Odẹ̀dẹ̀ tí wọ́n gbé ran okùn Ni wọ́n ti ń rẹ aṣọ o Díá fún Olọrí-ire Tí wọ́n ń fi ẹjọ́ ọ rẹ̀ wí kiri o Ebọ ní wọ́n ní kó wáá ṣe O gb’ẹ́bọ, ó rú’bọ Njẹ́ ení tí ńfi ẹjọ́ ọ̀ mi wí iriri Atórí Ifá ni yóó to t’èmí sí rere o Atòrí Afuera es para preparar tintes El pasaje es para darle vueltas A la soga El pasaje donde la soga Es abarcada Es también donde las Ropas son pintadas Estas fue lo profetizado A Olori-Ire Del que se estaba comentando De sus mal compartamiento Se le aconsejó que hiciera sacrificio Ahora, todos aquellos que comentan Que me comporto mal Que sea transformado Ifa transformará la opinión de la gente Sobre mi a favor mío Que sea transformado

Iwori Owonrin Bíiko bíiko gbàdàrà Gbàdàrà gbàdàrà bíiko A díá fún Iworìọ̀dẹ́rín ọlọ́pọ̀ obìnrin Ebọ n wọ́n ní ó ṣe O bá rúbọ O bẹ̀rẹ̀ síí láya Ayé yẹ ẹ́ Se ve como raffia y Muy largo

Muy Largo y se ve Como raffia Adivino para Iworioderin el esposa de muchas mujeres Se le aconsejó que sacrificará El ofreció los sacrificios Entonces comenzó a tener esposas La vida fue complaciente para él

Irosun Ogbe Irosùúngbèmí Elà gbé mí Elà pin pin pin Babalówo Iṣin ló Ṣ efá fún Iṣin Níjọ́ tí Iṣin ń fomi ojú ṣògbérè ire Oun le là báyìí? Oun le láya? Oún si bímọ? Ire gogbo tó òun lọ́wọ́? Wọ́n ní kí Iṣin ó rubọ Iṣín bá là Bi ọ́n ti jáwé ẹ̀ tó Irosun me enriquece Ela me enriquece Ela abriendo y cerrando El Babalawo de la manzana Akee Hizó adivinación para la manzana Akee En el día que la manzana Akee estaba Llorando por que no llegaban Todas las cosas buenas Tendré riquezas? El preguntó Tendré esposas? Hijos? Y poseeré buenas cosas en la vida? Le dijeron que hiciera sacrificio El así lo hizó La manzana Akee se volvió rica

Ogbe Di Ogbè Dí kàká Ogbè Dí Koko Ogbè di gànmùgànmu Irẹ̀ ma hàn Díá fún Eṣù Ọ̀dàrà

Ó n lọ fara ṣoọfà lọ́dọ̀ ọba mẹ́ta Ẹni tó ní òun ó f’Awo ṣẹ̀ṣín Ara rẹ̀ ló n ṣe Ẹkón araa won làwon n sun Àìwẹ̀ araa wọn làwọn n gbà Ogbe di kaka Ogbe di koko Ogbe di ganmuganmu Ire ma han Fueron los que adivinaron Ifa para Esu Odara Cuando iban a hacerlo un peón de tres reyes Aquellos que planificaron humillar un Awo Solo se humillarán así mismos Ellos lloran para si mismos Es su infortunio el que ellos lamentan

Obara Ogbe Ikú yòó Àrùn yòó Irunbi níí gbẹ́bàá ọ̀run fíofío Díá fún wọn lóde Ìdó Níjọ́ ajogun ká wọn mọ́lé pitipiti Ebọ ni wọ́n ní kí wọ́n wáá ṣe o Wọ́n gbẹ́bọ ó rùbọ Ikú ilé yìí kọ́ dẹrù Kó máa lọ o Òwìrìwìrì A ó finá Ifá wi wọ́n lára o Òwìrìwìrì Àrùn ilé yìí kọ́ dẹrù Kó máa lọ o Òwìrìwìrì Ẹjọ́ ilé yìí kọ́ dẹrù Kó máa lọ o Menciona todos los ayewo que quieras.... Permite que la muerte desaparezca Permite que la aflicción desaparezca Lejos y cerca del cielo esta el lugar en donde evadido Estas fueron las declaraciones de Ifa a los habitantes de Ido Cuando todos los males los seguían por completo Se les aconsejo ofrecer ebo

Ellos aceptaron Deja que la muerte en esta casa empaque su carga Y se vaya de aquí Owiriwiri Debemos tocarlos con el fuego de Ifa Permite que la aflicción en esta casa empaque su carga Y se vaya de aquí Owiriwiri Debemos tocarlo con el fuego de Ifa Menciona todos los ayewo que quieras....

Ogbe Bara Ogbè gbàràdà tán Tẹlẹ́gàn ló kú Ifá ṣeun gbogbo tán Ó ku tẹlẹ́nu Díá fún Ẹ̀dú Ọmọ agbápà lápà Ọmọ agbé rekete lóríi rekete Ogbe ha hecho maravillas Solo que los críticos no están satisfechos Ifa ha cumplido todas las cosas exitósamente Solo quedan calumniadores Estas fueron las declaciones de Ifa para Edu Aquel que acumula maravillas sobre maravillas Y amontona cosas maravillosas sobre cosas maravillosas Ogbe Yonu Inú bíbí ò da nnkan Sùúrù ní bàbá iwà Àgbà tó ní sùúrù Ohun gbogbo ló ní Díá fún Orí A bù fún Ìwà La paciencia es el padre de todas las características Un mayor que tiene paciencia Ese mayor tiene todo Estas fueron las declaracion de Ifá a Orí Y declaro lo mismo para Iwa

Ogunda Ogbe

Kùkùté ò mire jìgì Díá fún Lánkọsìn Ọmọ ajagun gbádé borí Ó ní ibi ẹ bá fọ̀rọ sí o Ẹ má mà jẹ́ kó yẹ̀ Awo ni kùkùté ò mire jìgì Awo ni Lánkọsìn Kùkùté ò mire jìgì Un tronco de árbol no se mueve de lado a lado Esta fue la declaración de Ifa a Lankosin Quien fue a la guerra y ganó una corona para adornar su cabeza El dice que cualquier cosa que concluyamos sea No dejes que cambie de ahí Kukute o mire jigi es un Awo Un tronco de árbol no se mueve de lado a lado

Ogbe Sa Afẹ́fẹ́ lẹ́lẹ́ níí ṣawo Ìsálú Ayé Ẹ̀fúùfù lẹ̀lẹ̀ níí ṣawo Ìsálú Òde Ọ́rún Kùkùte kùkùùkù, awo ẹ̀bá ọ̀nà Ògan yo lọ̀ọ̀lọ̀ jánà, awo eséko Díá fú Ikì Tíí ṣọ̀rẹ́ Àgbò-mìnìnjọ̀ La brisa gentil es el Awo de la tierra El viento suave es el Awo de los cielos El tronco pequeño pesado es el Awo de la orilla del camino Las viñas de Ogan que se arrastran a través del camino, el Awo de la granja Ellos fueron los que adivinaron Ifa para Iki Quien es un amigo muy cercano de Agbo-mininjo

Osa Ogbe Ọ̀sá lù Ogbè ń jó A díáfun Alágẹmọ Tẹ́ẹ́rẹ́ Ti ń sawoó rọ̀nà Àgbàlá Ọ̀nà Àgbà tóun ń lọ yìí dáa fún òun báyìí? Wọ́n ní yóó yẹ ẹ́ Wọ́n ní kí Alágemọ Tẹ́ẹ́rẹ́ ó rúbọ Ó dọ́nà àgbàlá ló fẹsẹ̀ kájé Owọ́ ẹ̀ ẹ́ tẹ gbogbo ire

Osa toca el tambor Ogbe esta bailando Vamos a aplaudir y usemoslo para bailar las campanas Aro Adivinaron para Alagemo Teere Que iba a aventurarse en el sacerdocio a Ona Agbala Será este lugar bueno para mi? Le dijeron que si lo sería Le dijeron que hiciera sacrificio Llego a Ona Agbala y este usaba sus piernas para acumular riqueza Su mano toco todas las fortunas que el deseo

Ogbe Otura Ajiwoye-ọdẹdẹ li o dífá f’Ọlọmọ-Agbeti Won ni: gbogbo inkan ti o maa ni Ọdẹdẹ ni wọn o maa wa baa Ebọ ní wọ́n ní kó wáá ṣe O gb’ẹ́bọ, ó rú’bọ Ajiwoye-odede adivinó para Olomo-Agbeti Se le dijo que todas sus adquicisiones vendrían fácilmente a él Se le dijo que ofreciera sacrifici El lo hizo

Otura Ogbe Alukerese-f’irakororin li o dífá f’Olokun-Ṣonde Wọ́n niki ó rúbọ nigbi ayé rẹ wa ni ṣẹnpẹnnẹ Wọ́n ni a di ńlá Ó gbọ́ ó rú Odi Ọba-Onibu-omi Alukerese-f’irakororin adivino para Olokun Sonde Que se sentó pacientemente a ver como la vida le pasaba por el lado Se le dijo que hiciera sacrificio cuando su vida parecía que ya no servía. Se le predijo que ella sería grande Ella escuchó e hizo el sacrificio Ella se convirtió en la reina de todas las corrientes de agua

Owonrin Ika Ọ̀wọ́nrín wonka-wónkà Odò ti’bi wáka-wàka ṣàn wá Díá fún Karare Tíí ṣọmọ Oníbú

Tó ńlọ síle ọkọ àárọ̀ Wọ́n ní kí wọ́n sákàalẹ̀, ẹbọ ní ṣiṣe Ó gbẹ́bọ, ò rúbọ Njẹ́ Kakara Kàṣàì bẹ́ja gbódò Kakara o Owonrin wonka-wonka El río fluye desde una estepa elevada Ellos fueron los que consultaron Ifa para la concha de mar La hija de los grandes mares Cuando planeaba ir a la casa de su esposo Se le aconsejó ofrecer un sacrificio Ella aceptó No importó lo que sucedió La concha ciertamente vivirá en el mismo río que el pez

Ogunda Otura Iṣu ú kú Iṣu ú fara jọ ọrọ Àbàtà sunwọn, sunwọn se gbẹ̀dẹ̀gún Díá fún Ọ̀kankànlékú Irúmọ̀lẹ̀ Wọn ńlọ rèé fẹ́ Ajere Tíí sọmọ Àjàlọ́run Díá fùn Ọ̀rúnmílà Ifá ńlọ rèé fẹ́ Ajere Tíí sọmọ Àjàlọ́run Ọ̀rúnmilà ló wá fẹ́ Ajere Tíí sọmọ Àjàlọ́run Njẹ́ Ìmọ̀nmọ̀ dá ki n ráyè Ki ń ri Ajere o Ìmọ̀nmọ̀ dá ki n ráyè Kí ń rì Ajere o El tubérculo del camte murió El tubérculo del camote parece cactus El lugar del pantano está seco y sereno Ellos fueron los que consultaron el Ifa para los 401 Irunmole Cuando fue a pedir la mano de Ajere La hija de Ajalorun Ellos también consultaron el Ifa para Orunmila Cuando fue a pedir la mano de Ajere Lahija de Ajalorun

Por favor deja que se ilumne para mi para poder ver Dejame sr capaz de ver a Ajere Deja que se ilume para mi para poder ver Permíteme ver a Ajere

Ogunda Fun Lékèélékèé kere léti ọpọ́n Òrúnmìlà Yọ̀yọ̀ọ̀yọ̀ níbẹ̀ A díá fún Òòsàálá Ọ̀sẹ̀ẹ̀rẹ̀mọ̀gbọ̀ Níjọ́ ti ń fomo ojú sògbérè ire gbogbo Wọ́n ní ú rúbọ Ayé àwọ́n le dáa báyìí?

Odi Ka Idinká èjiká Ejirọrọ èjirọ Gbòngbò tí ń bẹ ńnú omi ò leè kómi lẹ́sẹ̀ Kó dómi dúó láíláí A díá fún Ọ̀rúnmìlà Níjọ́ tí ń bẹ láàrin ọ̀tá sáńgílítí Ṣé àwọn elénìní yìí ò dá òun dúó báyìí? Wọ́n ní gbòngbò kan kìí gbénú odò kó Dómi dúó Wọ́n ní tí ọ́n bá làwọn ó dá ọ lọ́nà Ọ̀run ni wọ́n ó ti mọ́ọ mùkọ alẹ́ Ọ̀rúnmílà bá rúbọ Idinka ejika Ejiroro ejiro Las raíces de una corriente nunca pueden obstruir el curso del flujo de agua Adivinaron para Orunmila En el día en que el estaba en medio de sus verdaderos enemigos Estos detractores? No cruzaran y me pararan? Una raíz encontrada en el curso de una corriente nunca puede impedir el curso del flujo de agua Si ellos tratatan de interceptarte en tu camino Ellos comerán su próxima comida en el cielo. Orunmila entonces ofreció sacrificio

Otura Sa Ọ̀bábámbá Ọ̀mọ́mọ̀nmọ́ Ọ̀rọ̀ bẹ́nikàn mọ́ yọ̀rọ̀ bí ẹni tí ò tiẹ̀ gbọ́n A díá fún Wínnláwẹ̀ Obìnrin Àjàgùnmọ̀lè

Wínláwẹ̀ Obìnrin Àjàgùnmọ̀nlè ló jí ní Kùtùkùtù òwúrọ̀ Ní wá ń fomi ojú sògbérè ọmọ Ńgbà tí ó bìí Ó bí Agbe fún Ojolú Ńgbà tí o bìí Ó bí Àlùkò Dọ̀dòòdò fún Ojosùn Obabamba Omomonmo Oro benikan mo yoro bi eni ti o tie gbon Adivino para Winnlawe la descendencia de Ajagunmole Winnlawe la descendencia de Ajagunmole se despertó temprano en la mañana un día Ella lloraba por niños La primera vez que ella tuvo un niño Ella parión al bebé Agbe para Ojolu La próxima vez que ella tuvo un niño Ella tuvo a Aluko Doodo para Ojosun

Otura Irete Ọlọ́un ọba níí wọ́nfọ́n eji wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́ Àwòdì òkè níí rà gọrọnbi gọrọnbi lóríbè Bọ́lá bá ń wá nií bọ̀ wá Kòlẹ́dà ńnú mọ́ Ọ́ta inú omi ò gb’arinrin A día fún Àjòji gòdòdgbò Es Dios el que derrama la lluvia en torrentes dulces El águila del cielo es la que brinca hacia arriba y hacia abajo en las crestas de las montañas Si una fuente de riqueza viene a buscar a uno No hay necesidad de temer nuevamente La pequeña roca en la orilla del río no se preocupa por el frío Lo profetizado a Ajoji Godogbo

Osa Fun Ọ̀rúnmílà I Ọ̀sá-Fú Emii Ọ̀sá-Fú

A nṣa fun Ejò ki ejò ma baa bu’nijẹ A nṣa fun erin mabaa muni Adaa fun àwọn Enìyàn wọ́n niki awọn Enìyàn wa rúbọ kiwọn le maa Mọ ohun ti aisa fun ti anpe ni Eèwọ̀ Orunmila dijo Osa fun yo digo Osa fun Estamos corriendo de la mordida de la serpiente Estamos corriendo para que el elefante no nos agarre Esto fue lo profetizado a los hijos de los hombres a quien se le dijo que sacrificaran para que supieran de que huir aquello llamado tabú

Ofun Osa Òfún sà á sà á Ó sà á bẹ́ẹ̀ ni ò tán mọ́ A díá fún Ọ̀rúnmìlà Babá ń sunkún òun `la jé Wọ́n lẹ́bọ ajé ni kí Babá ó ṣe Ọ̀rúnmìlà bá rúbọ Ajé bá ṣẹ́ Ofun recogía y recogía El recogio contínuamente pero aún así todavía no se acababa Lo profetizado para Orunmila Baba lloraba por que no tenía riqueza Orunmila ofreció sacrificio El dinero comenzó a brotar de debajo de la tierra

Oshe Irete Láafià Àlááfià Èúùfù tó fé rékojá Kó má gbojùde bàbá á tèmi ló o Díá fún Séoro Tíí somokùnrìn àbàta Èyí tó soore láye

Láafia, paz Àlááfià, paz y tranquilidad La brisa que proporciona el soplido No soples pasando la calle de mi padre Estas fueron las declaraciones de Ifá a Séoró La descendencia de Abata, el área pantanosa

Irete Otura Ayé ni rére Àwòní jòjò Àwon ni wón dífá fún Òrun-un-mi-Òrun Àwon ni wón dífá fún Èla mi Èla Ifá jé kí n lówó Kí wón kí mi kú orí ire Ifá jé kí n l’áya Kí wón kí mi kú orí ire Ifá jé kí n bímo Kí wón kí mi kí orí ire Ifá jé kí n níre gbogbo El mundo es para siempre La piel es buena cuando brilla Estas fueron las declaraciones de Ifá para “Cielo, mi cielo” Ellos también declararon lo mismo para “Èla, mi Èla” Ifá, por favor bendíceme con riquezas Para que la gente me felicite por mi buena suerte

Ifá, bendíceme con una buena esposa Para que la gente me felicite por mi buena suerte Ifá, por favor bendíceme con buenos hijos Para que la gente me felicite por mi buena suerte Ifá, por favor bendíceme con todas las cosas buenas de la vida Para que la gente me felicite por mi buena suerte

Okana Yeku Awo ile Ajànkoro dúgbẹ́ Díá fún wọn ni ìlú Ajànkoro dùgbẹ́ Wọ́n láwọn ò ṣẹbọ, s’Oòṣà mọ́ Ajagun ló ká wọn mọ́le pitipiti Wọ́n gbẹ́bọ, wọ́n rùbọ Njẹ́ jànkoro dùgbẹ̀-dùgbẹ̀ A ti rúbọ Ebọ ọ́ dá ná o Ajànkoro dùgbẹ̀-dùgbẹ̀ Ilé mi mà jin Bí Ikú nlọ Kó rè wá mo ṣẹbọ o Ajànkoro dùgbẹ̀-dùgbẹ̀ Ebọ dà ná o Ajànkoro dùgbẹ̀-dùgbẹ̀ La punta de la espada no puede ser usada para verter aceite de palma en las fosas nasales El Awo residente de Àjànkoro dùgbè El fue el Awo que consultó el Ifá para ellos en Àjànkoro dùgbè Cuando ellos optaron por no ofrecer ebo o alimentar a los Orìsà otra vez Y ekl mal los rodeaba por completo Se les aconsejó ofrecer ebo Ellos aceptaron Ahora, Àjànkoro dùgbè-dùgbè Hemos ofrecido ebo Y nuestro ebo ha sido aceptado Àjànkoro dùgbè-dùgbè Mi casa está muy lejos Si la muerte está pasando

Mándale lejos de mi Àjànkoro dùgbè-dùgbè Hemos ofrecido ebo Y nuestro ebo a sido aceptado Àjànkoro dùgbè-dùgbè

Segundo Tablero Ogbe Iroso

Ọ̀nàgbọnrangọndọn-nti-Ifè-wa li o dífá f Abati tiiṣe aremọ Àramfẹ̀ eniti gbogbo ibi nkoriti Wọ̀n ni Ikú a gbee ti, Àrùn a gbee ti, Ẹjọ́ a gbee ti, Ofo a gbee ti Wọ́n niki o rú Agbo kan ati esé Ifá Ó gbọ́ ó rú Onagbonrangondon-nti-Ife-wa adivinó para Abati el hijo de Aramfe, que fue confrontando con todos los males Se le aseguro que la muerte no lo vencería La enfermedad no lo vencería El litigio no lo vencería Las perdidas no lo vencerían Se le dijo que sacrificaa un carneo y hojas de Ifa Obedeció y realizó el sacrificio

Otura Oshe Ọyẹrẹ orí imo li o dífá fun Òtú Òtú nlọ jagun ilú Ajaṣẹ Wọ́n niki o wa rúbo, a ṣẹ́gun Ó gbọ́ ó rú Ó ṣẹ́gun Oyere el del tope de la palma fue adivinado para Otu Otu iba a pelear una batalla en el pueblo de Ajase Se le pidió que sacrificara para que pudiera vencer El escucho y sacrifice y venció al enemigo

Tercer Tablero Aqui todavia no he hecho nada, pero se puede rezar Ojuani Shobe.

Cuarto Tablero Ìdí-Ófún Ìdí-Ófún ẹ̀bà yẹ ire Àgẹmọ òní ró mi Èkúté. Ní o bẹ̀rè Orunmila adífafún yọ̀ kó Ọbàtálá. Idi Fun se va acercando el beneficio de la buena fortuna. Agemo lleva hoy la noticia a Ekute. Tiene que inclinarse (hacer reverencia) a Orunmila lo profetizado en algarabía a Obatala.

Okana Osa Okànràn Osá o, elérù Igba Okànràn Olá ò r’ erù Ara nṣe Igún Igún ò yá ná Igba Okànràn Osá ò r’ erù Ara nṣe àkàlà Akàlà kò yá oòrùn Adiyẹ kàn gẹ́ ó d’ijẹ ẹnu D’ ifá fun Babaláwo mẹ́ta T’òhun irùkẹ̀rẹ̀ Ogun tí a jàà jà, tí kò ṣẹ́ Irùkẹ̀rẹ̀ l’Aládé fi ntú mọ̀ ọ wọn Tú imọ̀ ikú Tú imọ̀ àrùn Tú imọ̀ ẹjó Tú imọ̀ òfò Poner el ebo sobre el tablero Okànràn Osá, Babaláwo ọkọ̀ D’ifá fun ọkọ̀ O nlọ gúnlẹ̀ si èbúté Ibi ire ni ki ọkọ̀ mi ó gúnlẹ̀ sí Comenzar a girar nuevamente el ebo y recitar Okànràn Osá, Babalá ejò D’ifá fun ejò N’igbà ti ó nbẹ ni ‘rògun ọ̀tá Ibá ma ṣ’ọpẹ́ ori, à bá m ‘ejò d’igi l’óko Ori ejò ni ejò nṣẹ́gun

Igbá s’ojú d’ómi, ó ró tùbútùbú Oriji, afi iṣàn rẹ̀rẹ̀ D’ifá fun gbirari Eyi ti yóò kú l’áyé Ti yóò jẹ onibodè l’ọ́run Ki la ó ma pè ti a bá tubọ Abèràri la ó ma pé ti a bá tubọ Agbè wá gbè rààri (3 veces) Wọ̀rọkọ tii ṣe ọmọ iyá rẹ̀ (3 veces) Eṣù wa gbàá tètètè (3 veces)

View more...

Comments

Copyright ©2017 KUPDF Inc.
SUPPORT KUPDF